O se woo
O run woo
a kii ta Ogomo gbgbibe losun
Difa fun Orisanla Oseeremagbo
ti nlo ree gbe Ojose ni yawo
Oba nla, obi ose mi ree o
Oni lojo ose
O se woo
o run woo
No person paints a dry palm frond with camwood powder
IFA’s declarations to Orisanla Oseeremagbo
When going to marry Ojose as his wife
The Great King, here are my Obi Abata for Ose
Today is Ose
–
Ire O
Awo Fágbémijó Amósùn Fákáyòdé
OyekuOfun@yahoo.com