Afe kaye ni anfe ina, aran kaye lorun ni orun nran, eshinshin ki nmoni ki oto fi re ba eniyan, eyin omo araye efi oro rere lo mi loni.inu bibi ni nse obirin ogun , edo fufu ni nse obirin ija, ori aditu abiwa pele ni nse oko onisuru, aga inu bibi (NN)nko fi ise eni ran oo , edo fufu nko fi ise eni ran oo . Ti omode ati agba ki e wa de mi ni ade owo, oro emi gigun, alafia loni.Kabiyesi this is what IFA said today concerns you and I.Good morning ODUA A GBE WA AMIN ASE
October 29, 2015 at 9:14 am