Ebo A Fin Ebo A da , Ela Bami Gbebo Dode Orun Gbure Gbure, Ategbo Ateto, Niti Bara Mi Agbonminiregun Lotu Ife, OSA Ni Wole Deni Iwori Ni wo Ita, Adifa fun Awon Babalawo Mererin dinlogun Lojo ti Won nlo Ile Oduduwa Olofin lore Sawo, Kaye Olufe o le dara, kole Tuba Kole Tuse, Ase Ase Lori Aye gbogbo, Iwori Nseso adifa fun Baba Ajaguna Babalorisa Aye Gbogbo,,, Ori La findade
Ori Lafi Oba lorisa Je Lawujo Irunmale.
May 24, 2017 at 7:18 am

May 24, 2017 at 7:21 am
Ifa Yoo Gbe wa O , Orunmilla Yoo Pero si wa Lawo, Congratulations
May 28, 2017 at 12:02 am
Congratulation may Orunmila and 200 Deities be with you