Oyeku Ofun Temple

Ifa and Orisha Temple in Arcata, Humboldt County, Northern California // A Peaceful Place for Divine Worship

2 thoughts on “When the Ìrókò Tree Becomes Involved in Treachery, It Gets Felled

  1. GboGbo Ebo ti Aru Si Idi Iroko Oluwere Ara Lo Fi san, Baba Orogodo Gba , Baba Orogodo Gbu, Baba Igbo Ifa, Baba Igbodu, Baba Oshetura Dole Dole Dole, Baba Oluweeri, Iroko Abeta Yoonu, Iroko Ti Sawo Ilu Odan, Okiti Ogan , Ti Sawo Olu Igbo, Orogodo Gba Orogodo Gbu, Ifa Yoo Fi Oju Ota Mi Han, Orunmilla Yoo Fi Oju Ota Re Han, Olu Ebora Ti Ngbe Inu Ibu Omi Nla, Akoni Ekun ti nje Nikorita Meta, Ti Ndun Ko, Ko, Ko, Ogbontarigi Onisegun, Ti Nanja Oku ati alaaye Papo, Babalawo ti Npe Onisegun Rannise, Oluwo Nla, Babalawo Odu fun Baba Lorisa, Ire OOO

  2. Egungun Gogoro, Egungun Logoji, Egungun Mogaji Obaraka Shika Egungun Ile Oduduwa, Obaraka Shika Egun Ile Olofin Ondaye, Abijo Logba Logba, Adifa Fun Orunmilla Bara mi Agbominiregun, O wipe Loni Ni Ifa Yoo Fi Oju Ota Mi Han Leti Opon Ifa, Oka Awo Ile Elerin, Ere Awo won Ilabata, Yaya Sugudu Omo Olu Igbo, Okiti Ogan Pataki awo Ilu Odan,Iroko Igbo Abeeta Yoonu, Araba Pataki , Araba P ataki, Araba Pataki, Ni Sawo Won Ni Ile Epo, Oni Mo Mon Yin Edabo, Eyin Asheni Mo Monyin Edabo,, Okeere Fefe Ni Moti Mon Yin Ni Asheni, Eyin Asheni Mo Mon Yin Adabo, Orunmilla Ma Je Ki Asheni Ba Aye Wa Je Maje Ki Ibi Ba Ati Omo Ati Iyawo Wa o, Igba Odun Odun Kan nio, Ireo, Ire Ni Temi Tie ,

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s