Oyeku Ofun Temple

Ifa and Orisha Temple in Arcata, Humboldt County, Northern California // A Peaceful Place for Divine Worship

Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!

1 Comment

Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!

Erin wó
Àjànàkú sùn bí òkè
Lójú Olúgbọ̀n, bí i kí Orò má lọ
Lójú Arẹ̀ṣà, bí i kí Orò má lọ
Agbe dáró tán, Agbe ń lọ
Àlùkò kosùn tán, Àlùkò ń relé
Oyèwùsì Àmọ̀ó Fákáyọ̀dé ṣe tán, ó ń relé Ifẹ̀

An elephant has fallen
Left alone to Olúgbọn, it was as if Orò should not disappear
In the mind of Arẹṣà, it was as if Orò should stay till eternity
The blue touraco bird has finished making dye and gone
The purple touraco bird after making the camwood has dispersed
Oyèwùsì Àmọó Fákáyodé has finished his assignment in this terrestrial space, he is now transitioning to the celestial realm

With gratitude to Olódùmarè for the life well spent, we announce the transition of our father, the Patriarch of the Oyèkúnlé family of Oníbùdó Compound, Ìbàdàn, the Baálẹ̀ of Àlàdé Town, Ìbàdàn and the Àràbà/Olú-Ìṣẹ̀ṣe of Ìbàdàn land who joined the ancestors today Thursday, 28th November, 2019 around 11:30 am after 18 hours illness at the ripe age of 105.

Ẹlẹ́yẹlé
Aládìyẹ
Àmọ̀ó tí di awo ilẹ̀ mìíràn

Both sellers and buyers of pigeons
Both sellers and buyers of fowls
Àmọ̀ó has become priest in another realm

Kò pé òun ò ṣe mọ́
Ikú ló yọwọ́ rẹ̀ nínú àwo
Àgbà Ìṣògbó fọwọ́ okùn lélẹ̀ o

He did not withdraw consciously
It was death who removed his hands from the plate
An elderly priest has laid down his hand-decorated with okùn beads

Burial arrangements will be announced soon.

Signed:
Fayemi Fatunde Fakayode
For the family

One thought on “Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!

  1. Thank you for the information please accept my sympathy

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s